Àpapọ̀ Àwọn Gómìnà APC Ṣe Ìpàdé Inuyara Ní Ìpínlẹ̀ Kebbi
Progressive Governors Forum (Àpapọ̀ Àwọn Gómìnà Tí Ó Ń Tẹ̀síwájú) ń ṣe àpérò kan ní ẹnu ọ̀nà tí a fi pa mọ́ ní Ilé Ìgbìmọ̀ Council Chamber ti Ilé Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi ní Birnin Kebbi.
Hope Uzodimma, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Imo, ló jẹ́ alága fún ìpàdé Àpapọ̀ náà, tí ó ní àwọn Gómìnà tí wọ́n dìbò yàn lábẹ́ àsíá All Progressives Congress (APC).
Lára àwọn ohun tí wọ́n gbé kalẹ̀ fún ìjíròrò ni àwọn ọ̀rọ̀ pàtàkì ti orílẹ̀-èdè pẹ̀lú àwọn ọ̀rọ̀ tí ó kan ẹgbẹ́ olóṣèlú tí ó ń ṣàkóso.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Alága Ìpínlẹ̀ APC náà wà ní Kebbi, kò sí nínú ìpàdé náà.

editor's pick
latest video
news via inbox
Nulla turp dis cursus. Integer liberos euismod pretium faucibua

