Iroyin Titun

Ó Kéré Tan, Èèyàn Mẹ́ẹ̀ẹ́dógún Kú, Mẹ́ta Sì Sọnù Nínú Àjálù Ọkọ̀ Ojú-Omi Àwọn tó ń sá fún ìkọlù àwọn ọlọ́ṣà Ní Zamfara

  Èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ni wọ́n sọ pé wọ́n ti kú, [...]

By |2025-08-31T14:29:39+00:00August 31, 2025|Ìwà ọ̀daràn|0 Comments

Òpòló Chelsea ń tó, bí ọ́ bí ọ́, Nínú Ìdíje òun àti Fulham pẹ̀lú àmì ayò Méjì sí òdo (2-0)

Chelsea Kò Fọwọ́ Rọ́ṣẹ́, Ó Ṣẹ́gun Fulham Pẹ̀lú Góòlù Méjì [...]

By |2025-08-30T17:22:10+00:00August 30, 2025|Eré ìdárayá|0 Comments

Ògo Àdúgbò Manchester United bọ́ríyọ lónìí; Agbára òjò kò bá gbé wọn lọ ní Old Trafford.

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United ṣẹ́gun Burnley pẹ̀lú góòlù mẹ́ta sí [...]

By |2025-08-30T16:48:00+00:00August 30, 2025|Eré ìdárayá|0 Comments

Ẹnìkan Kú, A Gba Mẹ́sàn An Là, Ọmọ Ọdún 80 Sì Di Àwátì nínú Àjálù Ọkọ̀ Ojú-Omi ní Sokoto

  Àjàjà ìjàǹbá ọkọ̀ ojú-omi tí ó ń gbọn Ìpínlẹ̀ [...]

By |2025-08-30T07:11:50+00:00August 30, 2025|Irìnàjò|0 Comments

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ló Ku Nínú Ìjàǹbá Ọkọ̀ Ojú-Omi Ní Sokoto, Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Ìgbàlà

  Àjálù tún ṣẹlẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Sokoto ní Ọjọ́bọ̀ bí [...]

By |2025-08-29T20:19:12+00:00August 29, 2025|Irìnàjò|0 Comments
Go to Top