Gómìnà Nwifuru dá àwọn kọmíṣọ́nnà marundínláàádọ́rùn-ún (85) dúró, títí kan àwọn Akowe Pẹrmanẹnti, Olùrànlọ́wọ́ Pàtàkì Àgbà, àtàwọn mìíràn latari pé wọn kò ṣe ojúṣe wọn
Gómìnà Francis Nwifuru ti Ìpínlẹ̀ Ebonyi ti dá àwọn kọmíṣọ́nnà marundínláàádọ́rùn-ún, àwọn Akọ̀wé Àgbà, àwọn Olùrànlọ́wọ́ Àkànṣe, àti àwọn Olùrànlọ́wọ́ Àkànṣe dúró nítorí àìṣe ojúṣe wọn.
Àpapọ̀ àwọn tí wọ́n dá dúró náà ni àwọn kọmíṣọ́nnà márùnlélógún (25), Olùrànlọ́wọ́ Pàtàkì Àgbà mẹ́rìnlá (14), Olùrànlọ́wọ́ Pàtàkì mẹ́rìnlélógún (24), àti Akowe Pẹrmanẹnti méjìlélógún (22).
Nínú àtẹ̀jáde kan, Akowe Àgbà fún Ètò Ìròyìn fún Gómìnà, Dr. Monday Uzor, sọ pé idaduro lenu ise yìí jẹ́ fún oṣù kan láìsanwó.
Gómìnà tún pàṣẹ pé àwọn òṣìṣẹ́ tí a da duro kò gbọ́dọ̀ fọwọ́ sí ìwé ìkọ̀wé èyíkéyìí láàrin àsìkò idaduro wọn. Àwọn kọmíṣọ́nà náà gbọ́dọ̀ fi iṣẹ́ wọn lé àwọn Akowe Pẹrmanẹnti tí ó bá kan.
Gẹ́gẹ́ bí àtẹ̀jáde náà ti sọ, “Gómìnà Francis Nwifuru ti pàṣẹ pé kí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba tí a ṣe àkọsílẹ̀ wọn ní ìsàlẹ̀ yìí tẹ̀síwájú ní ìdádúró iṣẹ́ fún oṣù kan láìsí owó oṣù nítorí àìlọ sí ìgbòkègbodò ìjọba pàtàkì kan.
Àwọn tí wọ́n kan nínú idaduro yìí ni:
Àwọn Kọmíṣọ́nà:
Engr. Stanley Lebechi Mbam, Prof. Leonard Uguru, Dr. Mathew Nwobashi, Prof. Nwogo Obasi, Hon. Victor Chukwu, Engr. Jude Okpor, Barr. Ikeuwa Omebe, Hon. Chidi Onyia, Chief Oguzo – Offia Nwali, Dr. Ben. Uruchi Odo, Dr. Donatus Ilang, Dr. Mrs Ngozi Obichukwu, Dr. Moses Ekuma Ikenna, Chief Richard Idike, Barr. Mrs. Felicia Nwankpuma, Hon. Chinedu Nkah, Engr. Ogbonna Obasi Abara, Mrs Nkechinyere Iyioku, Engr. Francis Ori, Hon. Tochukwu Okorie, Barr. Valentine Okike Uzo, Chief Sunday Inyima, Hon. Ogbonnaya Okorie, Chief Elechi Elechi, àti Hon. Stanley Ogbuewu.
Àwọn Olùrànlọ́wọ́ Pàtàkì Àgbà:
Hon. Bassey Chukwu, Mrs. Rose Ofoke, Mr. Kerian Ofoke, Hon. Anthony Nwegede, Hon. Onu Nwonye, Mrs. Lilian Nwachkwu, Mr. Fred Nwogbaga, Hon. Paul Nwogha, Hon. Pius Nwoga, Hon. Ali Ikechukwu, Hon. Nwiboko Chukwuma, Mrs Esther Nwogha, Barr. Caleb onwe, àti Hon. Chinedu Awo.
Àwọn Olùrànlọ́wọ́ Pàtàkì:
Mr. Mbam Emmanuel, Tobias Ogbonna, Easy Okike Uzo, Obinna Oko Enyim, Chima Nnachi Okoro, Nwali Amechi, Dr. Sabinus Nwibo, Okorie Jideofor, Sunday Ogenyi, Stanley Kamani, Ikechukwu Jideofor, Emeka Okpa Onwe, David Aja, Frank Uka, John Nwangbo, Ogbonna Melford Nwuruku, Ifeanyi Ujebe, Chima Ogbuagu, Kizito Nwenyi, Uwa Henry Ifeanyi, Elechi Okechukwu Solomon, Ibina John Ogbonna, Mbam Ifeanyi D, àti Nwigum Nonso Christian.
Àwọn Akowe Pẹrmanẹnti:
Dr. Lawrence Ezeogo, Dr. Isioma C Arunne-Inyang, Mrs Rose Ibe, Mrs Ogechi Nwobasi, Mrs Anwu Theresa, Dr. Lynda Alo, Mr Monday Nkwuda, Mrs Mary Ngozi Otozi, Mrs Martina Obiya, Mrs Ogechi Anaso-Kalu, Barr Emmanuel Onwe, Mr Henry Nworie, Mrs Joy Mbam, Mrs Henrietta Ikechukwu Oruh, Barr Peter Ede, Dr. Gabriel Odo, Mrs Mfon Williamson, Ms Alusi Felicia, Mrs Betty Uzoma, Engr Chukwuma Ojeogu, Barr Ikechukwu Alobu, àti Mr Fidelis Nwankwo.
Orisun- Vanguard
editor's pick
latest video
news via inbox
Nulla turp dis cursus. Integer liberos euismod pretium faucibua