Skip to content

Ẹ káàbọ̀ sí Ìwé Ìròyìn Iroyin.ng, Lónìí ni: September 7, 2025

Iroyin Yoruba
  • Ìṣòwò
  • Ẹ̀kọ́
  • Ààbò
  • Ìjọba
  • ìlera
  • Ìròyìn Ayé
  • Iṣe-ọgbin
  • Awọn Mìíràn
    • Imọ ẹrọ
    • Eré ìdárayá
    • Ìròyìn Amúlùdùn
    • Àwọn Olókìkí
    • Ìwà ọ̀daràn
    • Iroyin Titun
    • Ìmúdọ̀tun
    • Oge
    • Ìtàn

Ìròyìn Ayé

  • Ìròyìn Ayé

    Ijọba Zambia sọ pé ibi ìwakùsà tó ti tú èròjà Asiidi eléwu jade teleri kò léwu mọ́

    Ọ̀gbẹ́ni Cornelius Mweetwa, agbẹnusọ ìjọba Zambia, kò fàyè gba ẹ̀sùn [...]

    August 7, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Ìjọba Central African Republic àti Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè ti bẹ̀rẹ̀ sí í tú àwọn ajàfità àtijọ́ sílẹ̀

    Ìjọba Orílẹ̀-èdè Olominira Central African Republic, pẹ̀lú àjọ àlàáfíà UN, [...]

    August 6, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Ijọba ilẹ Morocco ti fi ẹrù Ìrànlọ́wọ́ ranṣẹ si Gaza ni gègé àkọkọ́ kẹta, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Ọba wọn

    Àwọn oògùn àti oúnjẹ ń dé ibi tí wọ́n ti [...]

    August 5, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Trump Ti Fi Owo-ori Tuntun Lélẹ̀ fún Orílẹ̀-èdè Áfíríkà Mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n

    Ààrẹ Amẹ́ríkà, Trump, ti fi owo-ori tuntun lélẹ̀ fún ogún [...]

    August 1, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Awon Adájọ́ Ti Dá Trump Duro Lati Le Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-Èdè Honduras, Nepal, àti Nicaragua

    Onídàájọ́ ìjọba àpapọ̀ kan ní California ti dáwọ́ lílé àwọn [...]

    August 1, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Ìjà Olóró Láàrin Àwọn Ọmọ Ogun Uganda àti South Sudan

    Ìjà àjàkú-akátá tó wáyé láàrin àwọn ọmọ ogun Uganda àti [...]

    July 31, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Ghana Kọ Àkọsílẹ̀ Ikú Àkọ́kọ́ Nítorí Àrùn Mpox Bí Àwọn Àrùn Ṣe Ń Pọ̀ Sí I

    Ghana ti ṣe àkọsílẹ̀ ikú àkọ́kọ́ rẹ̀ látàrí Mpox, àwọn [...]

    July 27, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Àwọn ará Tunisia ń ṣe àtakò sí ààrẹ ní ọjọ́ ayẹyẹ ìgbà tí ó gba agbára

    Ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn ará Tunisia jáde sí ìgboro olú-ìlú, Tunis, ní [...]

    July 26, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Canal+ Gba MultiChoice Pẹ̀lú Òṣùwọ̀n $3bn, Ó Di Olùdarí DStv, GOtv Ni Kíkún

    Ilé-iṣẹ́ agbéròyìn Faransé, Canal+, ti gba àpapọ̀ ilé-iṣẹ́ MultiChoice Group, [...]

    July 24, 2025
  • Ìròyìn Ayé

    Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) bẹnu àtẹ́ lu àwọn ìkọlù Israẹli sí àwọn ilé-iṣẹ́ ní Gaza

    Àjọ Ìlera Àgbáyé (World Health Organisation (WHO) sọ pé ìkọlù [...]

    July 22, 2025
Previous234Next
iroyin yoruba

A ń mú ìròyìn tuntun àti ìmọ̀ ọ̀nà wá sí yín lójoojúmọ́!

  • Ilé
  • Nípà wa
  • Fi ìpolówó sílẹ̀
  • Pe wa

© 2024 - 2025 • ÌRÒYÌN.NG exclusive Yoruba News Platform • All Rights Reserved • Developed by Slushtech Solutions

Page load link

Press “ESC” key to close

main menu
  • Ìṣòwò
  • Ẹ̀kọ́
  • Ààbò
  • Ìjọba
  • ìlera
  • Ìròyìn Ayé
  • Iṣe-ọgbin
  • Awọn Mìíràn
    • Imọ ẹrọ
    • Eré ìdárayá
    • Ìròyìn Amúlùdùn
    • Àwọn Olókìkí
    • Ìwà ọ̀daràn
    • Iroyin Titun
    • Ìmúdọ̀tun
    • Oge
    • Ìtàn
Ìròyìn Tuntun
  • LASTMA curbs fire in Lagos road
    Àjọ LASTMA dá iná tó jó ọkọ̀ tó ń gbé epo rọ̀bì ní Iyana Isolo dúró
    Categories: Ààbò
  • NDLEA
    NDLEA Mú Agbájúgbà Oníṣòwò Oògùn olóró Pẹ̀lú Àpò ẹrù Loud àti Colorado Ní Ekiti
    Categories: Ìwà ọ̀daràn
  • Nottingham-Forest-v-West-Ham-United-Premier-League Getty Image
    West Ham fi àgbà hàn Nottingham Forest, O Si Gba Wọn Lulẹ̀
    Categories: Uncategorized
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Go to Top