Àwọn ọlọ́pàá gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ òfin mẹ́fà tí wọ́n jí gbé ní Benue
Ẹgbẹ́ ọlọ́pàá Benue, ní ọjọ́ Ẹtì, sọ pé àwọn ti gba gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́fà tí wọ́n jí gbé ní ilé ẹ̀kọ́ òfin Nàìjíríà, Yola Campus.
Ọga ọlọpaa to n ri si ibasepọ pẹlu awọn eeyan, DSP Edet Udeme, fi eyi han ninu atẹjade kan to fi sita fun awọn oniroyin ni Makurdi.
Udeme ṣalaye pe a gba awọn akẹkọọ naa ni owurọ Ọjọ Jimo.Gege bi o se so, awon akekoo naa, ti won n rin irin ajo lati Anambra si Adamawa, ni won ji lojo kerindinlogbon osu keje lori opopona Joota/Wukari Federal Highway.
“Wọ́n ti dá wọn sílẹ̀ tí wọ́n sì ti padà bá àwọn ẹbí wọn pàdé láàárọ̀ òní, Ọ̀jọ́ Kini osu Kejo.
“Wọn ji wọn gbe ni opopona Joota/Wukari Federal Highway, wọn si gba wọn la lọ si opopona High Tension Road, Wukari Taraba”, o fi kun un.
O salaye siwaju pe a gba awọn ọmọ ile-iwe naa pada atipe won mu wọn lọ si Ile-iṣẹ ọlọpa Divisional Ukum, ṣaaju ki wọn to darapọ mọ awọn idile wọn.
editor's pick
latest video
news via inbox
Nulla turp dis cursus. Integer liberos euismod pretium faucibua